Ogbo je eto kan pataki taa agbekale Latin ma so nipa awon agbalagba ati arugbo wa lawujo wa lati ma se itoju won ati aduroti won ni asiko to won wa. Eyi je ise Pataki fun enikokan wa ati awujo wa
See All 7 Episodes of "MrPeace Lagbolewa's podcast"