Ni ose ti o koja ni a ri bi Israeli ti ni isegun lori Jeriko nitoripe won gbekele eto ati ete Olorun nigbati won wa a fun itoni sugbon l'oni ni a wo abamo ati irora ti o gbehin awon omo Israeli nigbati won ko lati wa oju Olorun fun itosona ki won ki o to lo doju ija ko Ai...Joshua 7:1-13.....๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป....