Itelorun ni a le e pe ni ki eniyan wa ni aaye/ipo ayo ati ifokanbale koda pelu di e tabi binti....iyalenu ni o je bi a ti ojukokoro ati ainitelorun di ohun amuyangan/igbega ni awujo omoniyan ninu aye....loni, a o wo igbesi aye iranse Olorun kan ninu bibeli lati inu iwe filipi 4:4,6&7,11£12, 13.....darapo mo wa.....