Kini a n pe ni ironupiwada? Bawo ni a se le gbe igbese l'ati piwada kuro ninu awon iwa ogbologbo wa atijo? Gege bi a ti fun ijo Laodekia ni anfaani a ti ronupiwada ninu iwe Ifihan 3:18-22 ati ile Israeli ninu iwe Esekieli 18:21-23, 31&32 ni a fun emi 're ni iru anfaani nla banta banta yi o.....nje iwo setan l'ati pinnu l'ori ironupiwada?🤔🤔....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻.....