D'arapo mo wa l'oni l'ati jo wo iru agbara ati ase ti o wa ninu eje Jesu. Nje o ti e to si o? Ifihan 12:11....bi o ba si wa to si o, kini eri re? Nje o ti bi ara re ri ohun/awon ohun ti eri re je? Ko eko yi pelu wa.....๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘จโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป๐Ÿ‘ฉโ€๐Ÿ’ป