Eleyi ni eto yin eto wa,Yoruba Du'nka nibiti atima nka iwe Yoruba aladun si etigbo yin,iwe Yoruba ti a nka lowo ni OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMALE lati owo D.O. FAGUNWA.
Emi omo yin nani:
🎤Abdulhakeem Agbeyangi
Mc Warm up 🎶🎧
Aremo Enle faa 📻
08066342900.